Author Topic: KING SUNNY ADE FE DA RADIO STATION S'ILE  (Read 3249 times)

Offline SisiGbeborun

 • Jr Cadet
 • Posts: 4
 • Country: ng
 • Gender: Female
 • OS:
 • Linux Linux
 • Browser:
 • Chrome 28.0.1500.94 Chrome 28.0.1500.94
  • View Profile
 • Age: 31
 • Location: Abeokuta
 • Profession: Broadcasting
KING SUNNY ADE FE DA RADIO STATION S'ILE
« on: July 27, 2015, 01:28:35 PM »
Hehehe. . .  King Sunny Ade ti gbogbo eeyan mo si KSA ti setan bayi lati da ile ise radio (Radio Station)s'ile.  O ti pe die ti ise ti n lo l'ori radio station yi, ti o si je wipe igb'ohun s'afefe (Transmission) maa bere ki odun yi to pari.
Oruko ile ise radio yi ni M&C ti o tumo si Music and Culture.  Nigbati won beere lowo Sunny Ade wipe kilode ti o se pe ko to si radio station na, o ni ohun to ba ye ni sise, nise l'eeyan n se daada.
Sunny Ade se apejuwe M&C gege bi ile ise radio akoko ti o ma gbe asa ati orin ile wa l'aruge.

***Naija o ni baje o!

Advertisements


Nigerian Best Forum . NBF

KING SUNNY ADE FE DA RADIO STATION S'ILE
« on: July 27, 2015, 01:28:35 PM »

 

Enter Your Email Below For Daily Jobs Updates, It's Free

100% Free