Author Topic: Ado Oloro(Bomb) Kan Ti Bu Gbamu! Ni Somalia  (Read 2635 times)

Offline SisiGbeborun

 • Jr Cadet
 • Posts: 4
 • Country: ng
 • Gender: Female
 • OS:
 • Linux Linux
 • Browser:
 • Chrome 28.0.1500.94 Chrome 28.0.1500.94
  • View Profile
 • Age: 31
 • Location: Abeokuta
 • Profession: Broadcasting
Ado Oloro(Bomb) Kan Ti Bu Gbamu! Ni Somalia
« on: July 26, 2015, 08:04:42 PM »
L'ana ode yi ni a gbo wipe ado oloro(Bomb) kan bu gbamu ni Mogadishu - oluilu Somalia. 
Iroyin fi ye wa wipe ado oloro ohun ni won fi ranse si ile itura(Hotel) kan ti won n pe ni Jazeera.   Inu moto kan ni won ko awon ado oloro ti won fi s'ise ibi yi si.   O kere tan, eeyan mefa lo ti padanu emi won bayi.   Ni ijeta ni awon omo ogun Al Shabab nilu Somalia s'eku pa amofin agba kan, Abdulahi Hussein Muhamud ati awon oluso re.   www. sisigbeborun. blogspot. com

Advertisements

« Last Edit: July 26, 2015, 08:07:04 PM by SisiGbeborun »

Nigerian Best Forum . NBF

Ado Oloro(Bomb) Kan Ti Bu Gbamu! Ni Somalia
« on: July 26, 2015, 08:04:42 PM »

 

Enter Your Email Below For Daily Jobs Updates, It's Free

100% Free